Home Music : Sola Aro- Olowogbogboro

[New Single+Lyrics]: Sola Aro- Olowogbogboro

473
0
olowogbogboro
The upcoming UK based Sola Alo just released a new single titled “Olowogbogboro” produced by Shola Williams.

Olowogbogboro, a Yoruba titled track translates as “the Outstretched hands of God” in the English language expresses God’s ability to deliver and save His children from evil and dangers.

Sola is a writer, lawyer, an actress, a film producer,  a music writer /composer and a talented gospel singer. She has produced many albums and gospel hits over the years. She has created lots of inspirational songs in the Nigerian music industry. She is currently the CEO of a record label called PMP “PARADISE MUSIC & FILM PRODUCTION ” a subsidiary of “Paradise of Truth Ministry”
This is one song you should have on your playlist.
Download, Listen and Share

DOWNLOAD MP3
Follow us on Twitter

OLOWO GBOGBORO LYRICS

(Intro) uuuuummmm
Olowogbogboro  otiwole de
Olowogbogboro otiwole de…..

VERSE 1
Owole de, olowogbogboro wole de,
Oma wole de, oba to wo igba aisan wole de,
Isoro re ateriba, olubukun orun seri ibukun lewa Lori ,
Ilu ti ojagun fun lao fifun o,
Ibi ti ogbin si, wa ri ere konibe ,
Anu oluwa, yio sawari ire, gbogbo ire ato wa, olowogbogboro ti wole de..

CHORUS
Olowogbogboro ti wole de,
Olowogbogboro ti wole de,
Atun ayere to òré silekun okan re kogba re olowogbogboro olowogbogboro
olowogbogboro ti wole de…

VERSE 2
Bose wole de o, oniro banuje adalayo,
Aro Arin, afoju ariran,
Odi gbohun oluwa , agan aromo gbejo,
Àwon alaisan agba imularada, olowogbogboro wole de…

CHORUS 2
olowogbogboro, olowogbogboro olowogbogboro ti wole de…
MODULATION
olowogbogboro ti wole de,
Olowogbogboro ti wole de,
Atun ayere to òré silekun okan re kogba ire olowogbogboro olowogbogboro
olowogbogboro ti wole de….

Olowogbogboro olowogbogboro olowogbogboro ti wole de…

CODA
Silekun okan re kogba ire…