Home Music : Kay Wonder Ft. BeeJay Sax – My Father’s Love

[New Song+Lyrics]: Kay Wonder Ft. BeeJay Sax – My Father’s Love

347
0
my father's love
Inspirational praise and worship leader, Kay Wonder releases another soul lifting song, “My Father’s Love” where he featured fast-rising Nigerian saxophonist,  BeeJay Sax. The song talks about the boundless, endless, undying love of God towards us and the beautiful uncountable blessings we enjoy as His children.

The song is a song of gratitude to God as our anchor rests entirely on the assurance of His love towards us.

Download, Listen and Share
DOWNLOAD MP3
Follow us on Twitter

Lyrics
Verse 1

I have a father that cares for me
His Love is so boundless
His Love is so endless
He will never fail
.
I have a Father that cares for me
His Love is so boundless
His Love is so endless
He will never fail
.
I will follow you
until the very end
even if I fall
You will never leave me
Just like a prodigal son
You still welcome me back again
.
Chorus
.
Ese eyi tan o jo aye loju
Eyin saa ni father mi
gbogbo aye ti mo
pe e o loroogun
Eyin ni baba
to mo iyi omo
.
{BeejaySax}… Solo
Res…. Lalalalalalalala

Chorus
.
Ese eyi tan o jo aye loju
Eyin saa ni father wa
gbogbo aye ti mo
pe e o loroogun
Eyin ni baba
to mo iyi omo/2ce
.
Verse 2
.
Call…. Awa ni baba kan
Res…. Baba kan
Call…. Baba to iyi Omo
Call…. Baba to nke wa bi eyin
Call…. O pon wa bi omo
Call…. He’s the Father of the fatherless
Call…. Helper of the helpless
Call…. Hope of years to come
Call…. Helper in the time of need
Call…. Treasure of my heart / My Shield
Call…. Baba ayeraye loruko Yin o
Call…. Baba alanu
.
Chorus
.
E seyi tan,
o jo aye loju
Eyin saa ni father wa
Gbogbo aye ti mo pe e o loroogun
Eyin ni baba to mo iyi omo
.
Verse 3
.
E mo iyi mi
Jesu Emo iyi mi
E mo iyi emi omo yin “Kaywonder”
Jesu E mo iyi mi
Eyin le o je a Jalule
nigbati mimi aye ba mi wa,
Abiyamo Orun
ese ti e pon wa bi omo
.
Jesu
E mo iyi mi
Babaa mi
E mo iyi mi
atobajaye
Emo iyi omo
Yagboyaaju
E mo iyi omo yin
Eyin le o je a Jalule
nigbati iji aye ba mi wa,
Abiyamo Orun
ese ti e pon wa bi omo
.
Chorus
E seyi tan
o no aye loju
(Ise igbala te se fun wa)
eyin saa ni father wa
gbogbo aye ti mo
pe e o loroogun
eyin ni baba
to mo iyi omo
.
Coda…
.
Call….
Eyin ni baba olutoju wa
.
Res….
Baba Baba E ma see eyin baba to mo iyi omo,
.
{SanmiConga} Percussions……
.
{Epeeloruko}
{All echo}
.
Baba Baba
Eku ise
Lori oro aye mi
Eyin gan gan Lagba
otipe tipe t’e ti nba wabo
Gbegiiiiiiiiiiii…..{Echo of rejoicing}
.
{Holy Ghost chanting}
Agboo mati
Baaba mi agbalagba
olore akanse
oofi oope damu ologbon
ooso ologbon di oope
Eyin ni orisun
Agbongbe ibukun
Afi weeree Pari ise
Afi aikanju ko ni yo
ninu ewu idamu
Oba mi akiki tan ede
eniti ko ba mo Oba
lo n foba sere
Oba to mu ogun sinakerubu sun oorun ejika
Akooni ninu Awon Akooni  okunrin
Eyin ni babami.
.
Call…. Eyin baba Olutoju mi o
Res….Baba, Baba, E ma se eyin baba to mo iyi omo
.
.Baba o eyin ni baba o
All….
Baba ooo
Eyin ni baba o

Baba eyin ni baba o