Nigeria gospel songstress, Elizavocat is out with her latest new song titled, “ORUKO RE”.
The Name of the Lord is a strong tower and there is no greater power in heaven and on earth”. Oruko Re is a song that affirms all things is possible when the Name of Jesus is in charge. With him we know nothing will be impossible even as we journey through the storms. His name is more than jazz.
Download, Listen, and Share
DOWNLOAD MP3
Follow us on Twitter
Lyrics
Oh oh/2* Oruko re
Your name is more than Jazz
Oruko re jogunlo/2*
Je koruko re lana, ko lana fun mi ooo
Jekorukore lana ko Lana fun mi o
Jesu, iwo logun mi o oo
Ogun ajisa, ogun ajipe, ogun ajiyin, ogun ajibo, mope o loni ki n rowo,
kire wamiri, kaye fohungbogbo toje re wamiri
Ogun ti o l’overdose , ogun ti oni prescription, ogun ti ole baje lailai,
ogun ti ole womi, ogun ti ole sunko
Chorus: Je koruko re lana, ko lana fun mi ooo
Jekorukore lana kolana fun mi o
Seborukore sa nigbekele mi
Jesu, iwo logun tose gbarale, ogun ti ole dissapoint, ogun to ngbe ogun mi,
ogun to bori ogun, ogun to bori epe, ogun to n woni san lorukore, ogun to n
tunisile, ogun to n yoni ninu ofin,ogun to n renilekun,ogun to n ti ni
leyin ogun to n pani lerin, ogun to n yaye e ni pada si rere, ogun to n
saye eni dotun,ogun to n yi itan aye eni pada,ogun to n sogun dogo, ogun to
n sofo dogo.
Call: Oluwa
Resp: Je koruko re lana, ko lana fun mi ooo
Jekorukore lana kolana fun mi o
Your name,
Oruko re to san bi ara, oruko re to jabi iji, oruko re lo nu omije nu,
oruko re lo n taye eni se,
Oruko tokunrin npe, tobinrin npe
Tomode npe, Tagba npe, tagba npe to de n je lojojumo
Oruko to n dani nide, oruko to n wonisan, oruko to n lana fun ni, oruko to
fun ni ni ireti, oruko toje jewe ategbo lo.
Chorus: Je koruko re lana, ko lana fun mi ooo
Jekorukore lana kolana fun mi o
Ogun to nje/2*
Oruko Jesu ohun nikan logun to n je
Ogun ti ole expire lailai, ogun to nje, oruko Jesu nikan logun to nje
Ogun ti ole yeye eni, ogun ti oni expire lailai, oruko Jesu nikan logun to
n je
—